Luke 24:41
41
Nígbà tí wọn kò sì tí ì gbàgbọ́ fún ayọ̀, àti fún ìyanu, ó wí fún wọn pé,
“Ẹ̀yin ní ohunkóhun jíjẹ níhìn-ín yìí?”
Copyright information for
YorBMYO